E karo oo gbogbo omo Nigeria,Eku ojumo,ojumo to mowa laro yii - TopicsExpress



          

E karo oo gbogbo omo Nigeria,Eku ojumo,ojumo to mowa laro yii ojumore lomaje fun eyin ololufe me ,eku isinmi hmmm...Eyin mate mi lobinrin e ma ni gbegu elegu ooo,amen oo.eyin obinrin ni moba loro e shora fun jibiti ,ole ,olojukokoro okunrin , teba tiri ruwon keya shora oo okunrin teba tiwifun pe okomi monidi 5naira tio ri 50kobo mu sita ketete mo pe jibiti ara lofe lu. Okunrin koni sowa di ero eyin ooo .amen ooo
Posted on: Sun, 29 Sep 2013 01:34:01 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015