Mo fi asiko yi dupe lo wo gbo gbo eyin ti eti ba mi sise ri tabi - TopicsExpress



          

Mo fi asiko yi dupe lo wo gbo gbo eyin ti eti ba mi sise ri tabi kopa ninu film mi ri latori ero okan mi,aro olebi,palace of comedi,alujannu orun,iba ero,eyin mecca,chef qauteer,ago elepon,iba ero,ole ojo kan,ati,awo sobi, ti ase se pari ni aipe yi,bakanna awon ti mo ba wo dari re, eni kan lomo,idi ogun,osuwon ife,maseru e,esin obirin,ose je emi,iyawo jimo,ati ise awon omo ibo.meji ti mo dari ati awon mi ti mi ti ranti ati awon ti mo je ibakeji oludari fun mo ki yin pe ese gan,pe gbo gbo igba te yin na ba npe eyan fun ise wan ma je yin pelu ogo edumare,ati eni to koko ronu ise ti anse yi temi omo teyin omo afi olorun nikan pe ohun te ba ti ntoro ama ri be tori kose kose ni tilakose tomode ba mu ose ani ose ti agba ba mu ani ose ti yoin na ase ase ase lola abeni to to to !!!!!!!
Posted on: Sun, 17 Nov 2013 10:48:28 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015