Prayer for protection over our family members. Gbadura fun eniti - TopicsExpress



          

Prayer for protection over our family members. Gbadura fun eniti ibi / ajalu le kan ti yio kan wa, pe ki Olorun saanu fun wa.Btw 12 & 3am for 3dys. With Psm 91,23 & 27.( 1) gbogbo ohun to mu eru wonu aye mi, Oluwa jowo gbesele.(2) Tomotomo , tile tile a sa wonu apata ayeraye lo.(3). Fi ona ibi iserere awon omo mi siwaju won Oluwa.(4)Fi ese won si ibi iserere won Oluwa.(5) gbogbo ona ti kii se ona Oluwa, to le je irin ajo abamo. Mo ka kuro niwaju awon omo mi pelu idile mi IJN. Tiletile, tomotomo , tokotoko,mo ri wa bonu eje Jesu pelu aabo to daju. Obey & pls pass it to others including ur siblings. Sms to others not everybody can use BB. HGFBSF.
Posted on: Fri, 05 Jul 2013 14:06:22 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015