AARUN IKO (APA 3) E te siwaju, Ti Aarun Iko Yii Ba Si - TopicsExpress



          

AARUN IKO (APA 3) E te siwaju, Ti Aarun Iko Yii Ba Si Ngunji Orun(Persist): Ao fun Omi Eso Ayu (Garlic), ao lo Orogbo gbigbe, ao da Oyin Gidi sinu re, ao po po ao ma fun omode ni oogun yi ni iwon sibi imuko kan 1-1-1, agbalagba yoo ma mu ni iwon sibi imukomeji 1-1-1. Fun ekunrere idanileko ati iwosan to peye ni ilanna iwosan isegun ibile fun oniruuru aarun ati Ofa Ara(Spiritual Attack) e pe awon nombawonyi, 08065860161, 08054030581, 08186589781, tabi ki e kan si TDR (Chief) Sholaja Solanke Oluwatoyin. The Obaisegun (OSTHA) Lemode Zone,ni no 5, Samson Okeyemi Street, Ijoko Lemode Via Sango Ota, Ogun State.
Posted on: Fri, 30 Aug 2013 07:56:21 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015