ADURA FUN OJO ISINMI KEJO LEHIN METALOKAN Olorun Olodumare, oro Re - TopicsExpress



          

ADURA FUN OJO ISINMI KEJO LEHIN METALOKAN Olorun Olodumare, oro Re ni fitila si ese wa ati imole si ipa ona wa; Fi funni pe nipa kiko iwe mimo Re pelu suuru ki a le maa tele ona ti a gbe kale siwaju wa; nipase Jesu Kristi eniti o wa ti o si njoba pelu Re ati Emi Mimo, Olorun kan aye ainipekun. Amin. Olorun Olodumare, Iwo ti o ri pe awa ko ni agbara kan fun ara wa lati ran ara wa lowo: pa wa mo lode ni ara ati ninu okan wa, ki a le pa wa mo kuro ninu iponju gbogbo, eyi ti o le pa wa lara, ati kuro ninu gbogbo ero buburu eyi ti o le ko lu okan wa; nipase Jesu Kristi Oluwa wa. Amin. COLLECT FOR THE EIGHT SUNDAY AFTER TRINITY Almighty God, Your word is a lam to our feet and a light upon our path; grant that by patient study of the Scriptures we may follow more closely the way that You have set before us; through Jesus Christ who lives and reigns with You and the Holy Spirit, one God now and forever. Amen. Almighty God, You see that we have no power of ourselves to help ourselves; keep us both outwardly in our bodies and inwardly in our souls; that we may be defended from all adversities which may happen to the body, and from all evil thoughts which may assault and hurt the soul; through Jesus Christ our Lord. Amen.
Posted on: Sun, 21 Jul 2013 08:35:52 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics



1.

© 2015