ADURA OORO! Ni oruko Jesu Kirisiti, isoro ise wiwa lai ri ise - TopicsExpress



          

ADURA OORO! Ni oruko Jesu Kirisiti, isoro ise wiwa lai ri ise BI odun yi ti npari lo, o ya ma ri tire gba. Isoro airi owo na, aini owo lowo, loni ni OPIN de ba. Gbo iroyin ayo yi, omo OLORUN kan, pe mi ni ori fonu (phone) PE oun lusi kontirati kan, PE elomiran ni logba, Mo BI lere PE se o gbagbo, Nitoriti oro sope, Ti awon meji ba fi ohun won sokan BI won ba bere ohunkohun lowo OLORUN laisi ye meji, ao ri gba. O wipe beni sa, mo so fun PE kosi burobilemu, Ma LO o ti gbaa pada, omo OLORUN yi pe mi pada lojo keji pe Oun ti gba pada, ARA ninu OLUWA, BI wo na ba gbagbo, pelu mi laaro KI ile oni tosu ohun rere kohun rere, TI ati gba lowo re, PADA SI O LOWO NI ORUKO JESU KIRISITI. Ni ojo Jesu awon ise iyanu loju ese (instant miracles) po repeteee, nitori igbagbo awon eniyan igbana, BI otile jepe opolopo lori JESU OLUWA bii elese, Apere, (example) Johanu 9:20-30. Gbiyanju ki o ka o.
Posted on: Thu, 05 Dec 2013 05:22:10 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015