ALAROYE TOSEYI Adajo ti ju Tolulope to maa n ja soobu nIjesa - TopicsExpress



          

ALAROYE TOSEYI Adajo ti ju Tolulope to maa n ja soobu nIjesa sewon Igbejo te siwaju nile-ejo Majisreeti Musin Kin-in-ni lori ejo Olaniyan Tolulope ......................................................... ........... Lati Ilorin lAdisa ti loo jale lOsogbo, yoo foju bale-ejo Owo ileese olopaa ipinle Osun ti te omokunrin eni odun marundinlogoji kan, ......................................................... ........... LAkure, Dayo kowo fomo Ibo ko boun san an ni banki, niyen ba ko o sa lo Oro naa da bii ere ori-itage lOjoru, Wesde, ose to koja, niluu Akure, ......................................................... ........... Nitori oro ti ko to nnkan, Amaka da omi gbigbona ati kerosinni si ayalegbe egbe re lara Nitori esun tile-ejo Majisireeti to wa ni Yaba fi kan omobinrin eni odun mejidinlogun to je omoleewe girama kan lEkoo nibi, Amaka Egole, ......................................................... ........... Leyin to ba awon omo e soro ikeyin, iya arugbo jona mole l’Ondo Iku iya arugbo kan toruko reô n je Iyaafin Gbonjubola Akinnawonu, ......................................................... ........... Ayoade atawon egbe e jokoo sori reluwee daran, won ti wo won lo sile-ejo Nitori iwa arufin tawon okunrin metadinlogun kan hu pelu bi won se jokoo sori reluwee, ......................................................... ........... O ma se o! Awon agbenipa ran Balikis sorun l’Okeho Titi di bi a se n ko iroyin yii jo, a ko mo eni to seku pa iyaale ile kan, ......................................................... ........... Adajo ran Bateye to jale onile ni Musin lewon odun kan atosu meji Idajo waye nile-ejo Majisreeti Musin Kin-in-ni lori ejo Ali Bateye, ......................................................... ........... Muyiwa Adejobi, alukoro awon olopaa gba awoodu nla ni South Africa Lojo kejo, osu ta a wa yii ni ayeye kan waye ni Johannesburg, ......................................................... ........... Awon agbebonrin ya wo osibitu lEkiti, omo tuntun ni won fee ji gbe Bii idan nisele naa jo lojo Abameta, Satide, ose to koja yii nileewosan ijoba ibile kekere kan to wa lAdo-Ekiti, ......................................................... ........... Leyin odun mefa, ijoba fi agbejoro joba Alado Beeyan ba de ilu Ado to wa ni Sagamu lojo Isegun, Tusde, ose to koja, ......................................................... ........... Nitori aala ile, Ede ati Ido-Osun koju ija sira won Bi ijoba ipinle Osun ko ba tete yanju aawo to n fojoojumo sele laarin awon eeyan ilu Ede ati Ido-Osun, ......................................................... ........... Abiodun ti ko ju omo odun mejo lo, ko si kanga l’Ondo, owo baba re lo ji Manigbagbe gbaa lojo Isegun, Tusde, ose to koja yii je fawon araadugbo Fiwasaye, ......................................................... ........... Iyawo awon alaga onimoto fehonu han lAkure Pelu bi iyawo awon alaga garaaji ti won ti mole niluu Akure ......................................................... ........... Won n wa Ojogbon James Olomo Fun igba keji laarin odun mewaa, awon molebi atawon alabaasisepo Ojogbon James Olomo ......................................................... ........... Bi Father-u-Turn, olorin galala se ku ree Aaro ojo Aiku, Sannde, to koja yii niroyin aburu naa gba igboro pe gbajumo olorin galala ......................................................... ............... Tunde Balogun to dana sun awon eeyan merin lAbeokuta lojosi ti foju bale-ejo Se e ranti okunrin eni aadota odun kan, Tunde Balogun, ......................................................... ............... Nitori ti Tobi ja soobu onisoobu, adajo ni ki won fi sewon odun meji Adajo ile-ejo kan ni Isabo, niluu Abeokuta, ti pase pe ki won ju odomokunrin ......................................................... ............... Titi ti aye yoo fi pare ni akudaaya yoo maa wa —Oloye Ifayemi Elebuibon Awise ti ilu Osogbo, Oloye Ifayemi Elebuibon, ......................................................... ............... Tinubu ati Akande be Babangida lowe Bi eto ti awon asaaju egbe APC n se ba le yori sibi ti won fe ko yori si, ko si bi ijoba Naijiria ......................................................... ............... Rotimi atore e dero Kirikiri, obinrin ni won fipa ba lo po ninu moto Awon okunrin kan, Rotimi Olayanju, eni odun marundinlogoji pelu ore e, ......................................................... ............... Adajo ni ki Rafiu to pa omo odun mewaa loo se Keresi logba ewon Onidaajo Adebayo Lasisi ti ile-ejo Majisreeti kan niluu Osogbo ti pase pe kawon olopaa ......................................................... ............... Igbimo amusese awon olopaa ati araalu se ifilole kalenda Oga-agba olopaa ipinle Oyo, Mohammed Indabawa, ......................................................... ............... Won lawon Ode-Omi, nIjebu fee kuro labe ipinle Ogun Lati bii osu meloo kan seyin ni awuyewuye kan ti n lo lowo niluu Ode-Omi, ......................................................... ............... O ma se o, awon ajinigbe ji iya aadorun-un odun gbe sa lo niluu Owo Lowolowo bayii, ko ti i seni to mo ibi ti mama aadorun-un odun kan to je iya agba-oje ......................................................... ............... Nasiru saayan ladaa pa lEkiti, adajo ti ju u sewon Afurasi eni odun marundinlogoji, Nasiru Ibrahim, ......................................................... ............... Mukaila ba Muniru ja nitori fifti naira, lo ba subu lule, o ku Ija o dola, oruko ni i so ni lowe awon agba wi, ......................................................... ............... Nitori ti awon ore meta loo jale lagbegbe kan naa leemeji, won ti dero ile-ejo Awon okunrin meta kan, Mayowa Oguntoyinbo, eni odun mejidinlogbon; Basiru Raji, ......................................................... ............... Nitori to beere owo ile, Ayo foko fo lanloodu iya e lori l’Abeokuta Afi bii igba ti odomokunrin eni odun mokandinlogbon kan, Ayo Akanni ti kan oro lanloodu iya e monu tele lo ri, ......................................................... ............... Joshua fipa ba omoodun merin lo po, o ti wa lahaamo lEkiti Ile-ejo Majisreeti ilu Ado-Ekiti ni ileese olopaa wo okunrin kan toruko re n je Joshua .........
Posted on: Tue, 19 Nov 2013 08:09:59 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015