Agbara ase orun ni pe pepeye ko gbodo sun ekun lori omo re,eye ni - TopicsExpress



          

Agbara ase orun ni pe pepeye ko gbodo sun ekun lori omo re,eye ni pepeye,eniyan ati aworan Olorun ni iwo ise.Mo so sinu aye re pe,gbogbo omo ti a ko le o lowo,ati ti inu re pelu eyi ti o gba Olorun gbo fun,pe ni eyi ti o ku ki osu ati odun yi pari,o ni sun ekun lori won,omo araye o ni fi owo oran mu o lejika lori awon omo re.Gbo,lati oni lo ,ibi yowu ti awon omo re le wa,orun so won di symbol ogo fun iran won IJN.
Posted on: Tue, 23 Jul 2013 04:47:59 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015