Ani ninu oṣu kẹsan tawa yi baba fọrọ mi ṣeyanu. Jẹki - TopicsExpress



          

Ani ninu oṣu kẹsan tawa yi baba fọrọ mi ṣeyanu. Jẹki ọrọ mi koloju. Kọna ayọkola fun mi, kinba alanu bolere pade. Ṣilekun aanu rẹ fun mi, rọjo ibunkun ati itura re lemi lori. Ranmi lọwọ fopin si idaamu oṣi, aini ati wahala ninu aye mi. Jeki nrọwọ yọ larin ẹgbẹ ati ẹbi mi. Olufnimọna fimi mọna o, fi aṣo iyi atiẹyẹ bomi, bomi laṣiri, majẹki ọmọ arayeko ridi mi, majẹki wọn fi mi ṣe ẹlẹya, ṣe temi laṣepe, sọrọ mi dayọ, mu inu mi dun, mayọ mi kun oluwa. Edumare dakun dabọ gbọ adura mi, feti si ohunẹbẹ loni.
Posted on: Mon, 02 Sep 2013 04:57:16 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015