Bi a se le kọ ọmọ wa ti ko ni fi ya iya ku ya ni wipe ki a - TopicsExpress



          

Bi a se le kọ ọmọ wa ti ko ni fi ya iya ku ya ni wipe ki a kọ iha ti o da si ọmọ naa, paapa ju lọ ni igba ti abi ọmọ ti o ma fi di ọdun marun. Sungbọn a bọdọ jẹ ki ọmọ naa o yọ ju, bẹ a si tun bọ dọ jẹ ki iya o jẹ, ki wahala mọ ba waye (FIXATION) ninu igbese aye ọmọ naa. Ọjọgbọn Segmund Freud lo fi ye wa bẹ::::::::: MO KI GBOGBO AWA MUSULUMI PE A KU IPALẸ MỌ ỌDUN,INU DUN LA MA FI SE (AMIN):::::::
Posted on: Tue, 06 Aug 2013 04:50:26 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015