Bibeli wipe eniti o joko nibi ikooko oga ogo ni yio ma gbe Abe - TopicsExpress



          

Bibeli wipe eniti o joko nibi ikooko oga ogo ni yio ma gbe Abe ojiji re. Nitori ti awa gbekele oba adeda aseda awa yio ma wa ni Abe ojiji olodumare titi aiyeraiye.bi iku npa lotun losi koni sun mo gbogbo wa.igbekele wa si olorun koni jasi asan.ose ayo.idunu.anu.alafia.ifokanbale ni.ose yi yio je fun wa.ti a ba ri eni to nrerin siwa to nfinu bawa ja.Oba ti o pase fun ile to datani oun aboramu mi nigba ti won sote soluwa.orun yio Pase ile yio si lanu gbe won mi.yio gba wa sile lowo aninilara ati onilara eniyan amin friends
Posted on: Mon, 05 Aug 2013 04:32:55 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015