OLUWA li oluse-agutan mi;JIDE AFOLABI emi ki yio se alaini.O mu mi - TopicsExpress



          

OLUWA li oluse-agutan mi;JIDE AFOLABI emi ki yio se alaini.O mu mi dubule ninu papa-oko tutu;o mu mi lo si iha omi didake roro.O tu okan mi lara;o mu mi lo nipa ona ododo nitori oruko re.Nitoto bi mo tile nrin larin afonifoji ojiji iku, emi jide omo afolabi ki yio beru ibi kan,nitori ti lwo pelu mi,ogo re ati opa re nwon ntu mi nimu.Iwo te tabili onje sile niwaju mi li oju awon ota mi,iwo da ororo si mi li ori ago mi si kun akunwosile Nitoto, ire ati anu ni yio ma to mi jide lehin li ojo aiye mi gbogbo, emi o si ma gba inu ile oluwa lailai
Posted on: Thu, 26 Sep 2013 06:34:09 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015