Oluwa ni oluso aguntan mi emi ki yio se alaini o mu mi dubule ni - TopicsExpress



          

Oluwa ni oluso aguntan mi emi ki yio se alaini o mu mi dubule ni papa oko tutu o mu mi lo si iha omi didake roro o tu okan mi lara o mu mi lo nipa ona ododo nitori oruko re nitoto bi mo tile nrin larin afonifoji iku emi ki yio beru ibi kan nitori iwo pelu mi ogo re ati opa re nwon ntu mi ni inu iwo te tabili onje sile niwaju mi ni oju awon ota mi iwo da ororo si mi ni ori ago mi si kun akunwosile nitoto ire ati anu ni yio to mi leyin ni ojo aiye mi gbogbo emi o si ma gbe inu ile oluwa lailai
Posted on: Sat, 19 Oct 2013 11:58:21 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015