Osu yi sese bere ni, ayo mi, ayo re sese bere ni. Oluwa yio pase - TopicsExpress



          

Osu yi sese bere ni, ayo mi, ayo re sese bere ni. Oluwa yio pase iyanu, igbega, ilosiwaju, ibukun ati isegun sinu aye temi tire ati gbogbo ona wa. Bi a ti njade lo loni, ninu osu titun yii, ojurere ati aanu Oluwa yio ba gbogbo wa pade, yio wa wa ri. Gbogbo idawole, idasele wa ninu osu yii ni yio yori si rere lagbara olorun. Amin! The new month just started, so is my joy and yours. It is decreed from the Lord promotion, developement, blessings, marvelous things, wonderful victory and total breakthrough over every areas of our lives. As we go forth this day in this new month, the favor and mercy of God shall make way for us, and we all shall prosper in all that we lay our hands on to in the mighty name of God. Amen!
Posted on: Tue, 02 Jul 2013 11:25:31 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015