¤THIS NEW WEEK SHALL PLEASE ALL THE FANS OF THIS - TopicsExpress



          

¤THIS NEW WEEK SHALL PLEASE ALL THE FANS OF THIS PAGE(Amen)¤ Oriotolu, Ayajinmo giri, Sunkungbade omo ato. Oseminigbokun omo igbomini. Ajibowu alagbede orun, lagbaranwun lonisona ibe. Owawa ode ile aye. Gbuede ode orun, Onibode oniwowo jiwowo. Ajagunna ode idena. Kindinrin awo ideta. Sekunda awo oranmiyan. Elese awo ile oyan, Erinmi awo ode owo. IBA OLODUMARE OOO!. Eje ki ose yin san awa tile toko(ase!). Kori awa sunwon lose yi, gbogbo wa karire patapata porogodo. ase!.
Posted on: Mon, 18 Nov 2013 04:59:46 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015