(KOKO ADURA MEJE FUN AYE RE) (1) Ninu odun yi, imole ogo re yio - TopicsExpress



          

(KOKO ADURA MEJE FUN AYE RE) (1) Ninu odun yi, imole ogo re yio tan. (2) Ninu odun yi, iwe igbega yio te o lowo (3) Ninu odun yi gbogbo idawole re ni yio yori si rere. (4) Ninu odun yi, won o nii fi aso iku bo o.(5) Ninu odun yi, Ariwo ekun ko nii ta ninu ile re. (6) Ninu odun yi. Olorun yio so o di ogo ayeraye. (7) Ninu odun yi, o o nii mo ibanuje, ekun, ofo, ijamba ko ni je tire ati idile re ni oruko Jeeeeeeesu. Amin
Posted on: Thu, 26 Sep 2013 06:24:31 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015