Mo palase loni ni Oruko Nla Olorun Awon Omo Ogun gbogbo adehun - TopicsExpress



          

Mo palase loni ni Oruko Nla Olorun Awon Omo Ogun gbogbo adehun iku, ipinu iku ojiji, isa oku lori re ati gbogbo ebi re la o pa re loni. Emi re yio se opin odun yi, yio si se amodun. Emi gigun, ilera ati alafia la o fi da o lola, ta o lore. I declare and proclaim today in The Mighty Name of God of Host any agreement with death, untimely death, hell and the grave made over you and your entire household is broken today. You shall not only witness the end of 2013, but shall also celebrate 2014 and many more. Long life, good health is bestowed upon you.
Posted on: Thu, 05 Sep 2013 06:55:49 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015