OPO KINI ESIN ALAFIA NI IMO OLORUN LOKAN:~ Imon Olorun ni okan - TopicsExpress



          

OPO KINI ESIN ALAFIA NI IMO OLORUN LOKAN:~ Imon Olorun ni okan soso, kobimo beeni enikan ko lee bi Olorun. Ohun nikan soso ni nsola ninu ogo Re. Awon akosile iwe isin Olorun (Bible & Qur'an) pelu toka eyi fun wa pelu awon eri ti o daju pe okan soso ni Olorun. Ni eyiti o je opo akoko fun gbogbo olugba Olorun gbo ni ododo, laije amulumala isin. atipe awon aaye itoka oro Olorun fi han wipe ojise Olorun ni Muhammad ati Jesu je, ati gbogbo awon ojise ti o ku ti owa si aiye pelu. QUR'AN: "قل هو ألله أحد* ألله الصمد* لم يلد ولم يولد* ولم يكن له كفواآحد* Wipe:~ "On Olorun okan soso ni, Olorun ni Eniti gbogbo eda nronu kan (gbeke le) ko bi omo beeni a ko biI. ko sin si enikan ti o da bii Re".
Posted on: Wed, 03 Jul 2013 09:54:49 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015