SERVING CHRIST IN OTHERS “But if anyone has the world’s goods - TopicsExpress



          

SERVING CHRIST IN OTHERS “But if anyone has the world’s goods and sees his brother in need, yet closes his heart against him, how does God’s love abide in him? Little children, let us not love in word or speech but in deed and in truth” - I John 3:17-18b. The word of the Lord makes it clear that serving the Lord is not just about keeping religious ordinances - it is not about verbal confession of faith or ability to sing God’s praise. The fact remains that our level of faith is expressed not in our many utterances, but in our deed. Serving God is in ACTION. And there is no way to show our commitment to God except by the way we respond to one another’s needs. The parable of the Good Samaritan summarized the whole of our duties as servants of Christ (Luke 10). Our service to God is not measured by ordination, position in church or title, consistency in church services, confirmation, or year of membership in the church; financial commitment like tithing and paying endowments, etc. All these are good and indeed obligatory but, our service to God is measured by our disposition to other brethren, especially the needy. Exodus 22:25 - Take not interest, when you lend to the poor. Exodus 23:3,6 - Do not be partial to the poor nor pervert their justice. Exodus 23:11 - Give the excess of your income to the poor. Taking a critical look at the teachings of Christ, we will discover that the best way to serve Him is by serving others. If you want to be a leader, be the servant of others. If you want to inherit His kingdom, be kind to other people around, especially the little ones. Finally brethren, whatsoever things are true, whatsoever things are honest, whatsoever things are just, whatsoever things are pure, whatsoever things are lovely, whatsoever things are of good report: if there be any virtue, and if there be any praise, THINK ON THESE THINGS - Philip. 4:8. SISIN KRISTI LAT’ARA AWON ELOMIRAN “Sugbon eniti o ba ni ohun ini aiye, ti o si ri arakunrin re ti i se alaini, ti o si se ilekun iyonu re mo o, bawo ni ife Olorun ti ngbe inu re? Enyin omo mi, e mase je ki a fi oro tabi ahon feran, bikose ni ise ati li otito ” - I Johannu 3:17-18. Olorun fi han wa gbangba pe, sisin Oluwa ki i se nipa pipa asa ati ilana esin mo nikan. Ki i se nipa ijewo oro enu lasan tabi mimo bi a ti kokiki Olorun. Ki o ye wa daju pe titobi igbagbo wa kii se nipa oro enu lasan la fi nmo bikose ninu ise wa. Sisin Olorun ni i se pelu ISE. Ko si si ona ti a le fi itara wa fun Olorun han bikose nipa ihuwasi wa si aini elomiran. Owe nipa okunrin ara Samaria se alaye kukuru nipa ohun ti ise isin wa tumosi gegebi iranse Kristi (Luku 10). Ki i se ami ororo la fi nwon ise isin wa, tabi ipo, oye ninu ijo, sise deede ninu isin, owo sisan bi idamewa, ore tabi sisan owo egbe ati bebelo. Gbogbo awon ise isin yi lo dara ti o si se dandan fun wa, sugbon, ise si wa si awon ara wa miran ni opolopo lati se pelu bi a ti nsin Olorun; nipataki, isesi wa si awon alaini. Eksodu 22:25 - Mase gbe ele lori owo ti o ba ya talaka. Eksodu 23:3,6 - Mase se ojusaju si talaka, ma si se yi idajo po. Eksodu 23:11 - Je ajeseku fun awon ti ko ni. Nigba ti a ba fi ara bale wo awon eko Kristi daada, a o ri pe ona ti o dara ju lati sin Olorun ni ki a se iranse fun awon eniyan. Bi iwo ba fe je adari, ko bi a ti i se iranse fun awon eniyan. Bi iwo ba fe wo ijoba Olorun, se rere si gbogbo eniyan ti o yi o kaakiri ni pataki, awon kekeke. Lakotan ara, ohunkohun ti ise otito, ohunkohun ti ise owo, ohunkohun ti ise tito, ohunkohun ti ise mimo, ohunkohun ti ise fife, ohunkohun ti o ni irohin rere, bi iwa tito kan ba wa, bi iyin kan ba si wa, MAA GBA NKAN WONYI RO - Filip. 4:8
Posted on: Sun, 04 Aug 2013 18:15:06 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015