ÒKODORO Ọ̀RỌ̀ (Pure Fact): Húùm..ìdá ìlú ní ìsèlú - TopicsExpress



          

ÒKODORO Ọ̀RỌ̀ (Pure Fact): Húùm..ìdá ìlú ní ìsèlú àti ìsesí láwùjọ; a dífá fÉgúngún tó ńgbowó lẹ́nu ibodè íbìkan!!.. Lèyí tó já sí wípé bí a bá dé ilú àwọn afọ́jú, ní se ló yẹkí a fọgbọ́n dijú; bí a bá sì dé tẹ̀dó sìlú àwọn adẹ́tẹ̀, bí a sọwọ́ kúdúrú kò lèèwọ̀!!. Translation: Huum...custom of the land dictates its political and social inclination, necessitating a Masquerade serving as an Immigration officer of a particular place!!. Thus, if you get to a place of the blinds, you must learn how to act as a blind; if you settle in a city of lepers, learning how to fold your palms there shouldnt be a taboo!!.
Posted on: Mon, 10 Nov 2014 13:14:51 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015