ABEOKUTA ILU EGBA ILU LISABI AGBONGBO AKALA ILU LAMODI OJULOWO - TopicsExpress



          

ABEOKUTA ILU EGBA ILU LISABI AGBONGBO AKALA ILU LAMODI OJULOWO BALOGUN ILU ORI OKE OUN PETELE ILU AJIBOYEDE TOFI OMO RE TUNLE SE ILU SODEKE OMO EFUWO AKONI ATATA ILU AROBI OLOGBO EGAN OJULOWO ODE ILU AWON AGBA OJE NINU ISE IDAJO ILU LOOKO LOOKO NINU ISE OBA ILU TI EGBA AKE TI SONA ILOSIWAJU IBITI EGBA OWU TI N SARE IGBEGA ILU TI EGBA AGURA TI N FON RERE IDAGBASOKE BEE LEGBA OKE ONA OYE POLONGO ITESIWAJU EGBA IBARA OSI DEKUN AYAN ITUNLUSE ILU TI GBOGBO EGBA TI N FIFELO ILU ABE OKUTA ABE OLUMO A-BE-LORO I AM PROUD OF MY ORIGIN
Posted on: Tue, 30 Jul 2013 10:08:51 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015