ADURA FUN OJO ISINMI KOKANLA LEHIN METALOKAN Olorun Olodumare, - TopicsExpress



          

ADURA FUN OJO ISINMI KOKANLA LEHIN METALOKAN Olorun Olodumare, eniti o pe ijo Re lati jeri wipe O wa ninu Kristi, O si mba eniyan laja sodo ara Re: ran wa lowo lati kede, nipase ihinrere ife Re, ki gbogbo awon ti o ba gbo O le ba O laja, nipase eni to ku fun Wa, ti O si tun jinde ti o si njoba pelu Re ati Emi Mimo, Olorun kan, nisisiyi ati titi laelae. Amin. COLLECT FOR THE ELEVENTH SUNDAY AFTER TRINITY Almighty God, Who called Your Church to witness that You were in Christ reconciling men to Yourself, help us to proclaim the good news of Your love, that all who hear it may be reconciled to You; through Him Who died for us and rose again and reigns with You and the Holy Spirit, one God now, and forever. Amen.
Posted on: Sun, 11 Aug 2013 06:55:33 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015