Adura yii tun wa fun eniyan 30 pere Ni aaro yii, Ibukun ni fun mi - TopicsExpress



          

Adura yii tun wa fun eniyan 30 pere Ni aaro yii, Ibukun ni fun mi ni ilu,Ibukun ni fun mi ni oko pelu, Ibukun ni fun omo inu mi ,ati eso ile mi,ati awon ohun osin re, Ibukun ni fun mi nigbati o ba wole, Ibukun ni fun mi nigbati mo ba jade Oluwa yoo mu awon ota ti o ba dide simi di eni ikolu ni iwaju mi,won o jade simi ni ona kan,won yoo si sa ni ona meje, Oluwa yoo si pase ibukun sori mi, ati lori gbogbo oun ti month ba dawole,on yoo si busi fun mi, Oluwa yoo si fimi se ori, emi ki yoo si se iru,Amin Amin Amin ni oruko Jesu let me see ur Amens below, U r blessed
Posted on: Wed, 24 Jul 2013 06:05:29 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015