And the angel answering said unto him, I am Gabriel, that stand in the presence of God; and am sent to speak unto thee, and to shew thee these glad tidings. (Luke 1:19 KJV) Jehovah,JESU KRISTI,Michael MIMO OLUWA OLORUN celestial, Oba TI GBENU OGO to tun shogo NINU OGO OLORUN S,B,J,OSHOFFA LONI OJO AKOKO NINU OSU TUTU YII, E RAN AWON MALEKA YIN JADE LATI IGUN MERIN AGBAYE KI WON WA FI IBUKUN,IGBEGA,ASEYORI,ATI ASEYEGE, OGO TI KO NI PEGUN FUN AWA OMO RE, GBOGBO KOKORO ASEYORI, GBOGBO KOKORO ASEYEGE,GBOGBO KOKORO AGBARA EBU EMI MIMO YIN, E WA FILE AWA OMO RE LOWO LATI ONI LO ATI TITI LAI,AMIN HAPPY NEW MONTH TO YOU ALL ONE LOVE NANI O. — feeling blessed.
Posted on: Tue, 01 Jul 2014 07:27:12 +0000