Bi otin jade lo loni, oju oluwa kio ma ba e lo, agbara olohun ko - TopicsExpress



          

Bi otin jade lo loni, oju oluwa kio ma ba e lo, agbara olohun ko tie leyin, wari anu gba, gbogbo awan otere ti won dide sioo ki won di enikolu, iranlowo lati ibi †̥ gaa ko dide fun oo, olohun kio gbe o pade olore, ni oruko olohun oba kio pade alanu, agbara aseyori tio sonu ni inu ayere olohun dapada, letter ayo re kio gba, aseti yen okuro ni nu aye re, oriburuku yen aso di ori re, oti ri be beni kori [amin]
Posted on: Sat, 29 Jun 2013 12:10:27 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015