Glory be to god today is my birthday oni ni ojo ti inu mi dun ju - TopicsExpress



          

Glory be to god today is my birthday oni ni ojo ti inu mi dun ju lo nito oni ni ojo tia bimi sile aye yii mo un wa fi asiko yii toro lowo olorun oba ojoke aye asake lode oru wipe gbogbo un ti eniyan fi man un lo ile aye ki olorun kio pese re fun mi gbogbo un ti eniyan fun lo. Igba ti eniyan fi un lo odun gbogbo re patapata nimo toro lowo olorun ki odun yii kio. Je. Ajele odun fun mi igba odun kio je odun kan fun mi oo gbogbo ohun ti moba dawo le kio ja si rere loju aye mi kiun mase toro je lowo ota mi gbogbo arogba mi si rere ki olorun kio je ki owa si imuse iyawo alalubarika nimo fi asiko yii toro lowo olorun ki olorun kio jogun re fun mi moki gbogbo eyin ololufemi eyin ore mi eyin egban mi aburo ati eyin tie to baba fun mi ati eyin tie to iya fun mi aladugbo omo ilu mi mosi ki gbogbo eyin omo isoko irodun tile toko igba odun odun kan ni fun gbogbo wa patapata oooo amin amin amin loruko jesu ese emini tiyin toto ayansesan omo ayangbemi iba olorun iba eniyan iba iya mi iba baba ayangbemi omo agbansafara tio ri oro se bi oyin odabo
Posted on: Thu, 08 Aug 2013 05:47:29 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015