Hum oro ngbe mi lokan si awa obi,nje amo wipe awa ni ileko akoko - TopicsExpress



          

Hum oro ngbe mi lokan si awa obi,nje amo wipe awa ni ileko akoko fun awon omo wa? Owu ti iya ba gbon lomo oran,iwo ti o pe ara re ni obi ti fi gbogbo ara ya cartoon si,o ya titi oya cartoon oyan re ati ibadi re,eko wo ni o fun awon omo re?iya opopnu ti o fi ara bibo se gbajumo ofoerun ojo ekun re ku ola. Baba oponu iwo naa so oti mumu se gbajumo, o mu oti ohun tan wa ma subu kiri adugbo,won ti mo e ni baba ologogoro, oju re ti wa loyun. Jowo ma ba ojo ola awon omo re je. Ninu tira awon olorin kan o so wipe thank you daddy mi wipe o ki nse oloti,nitori awon ore mi won ma bu mi ti e ba subu kakiri. Ronu re ki o pa iwada.
Posted on: Mon, 24 Jun 2013 10:18:49 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015