Huum...a question as to whether the sour mouth is already healed - TopicsExpress



          

Huum...a question as to whether the sour mouth is already healed or not is out of place for someone who pointedly finished a whole plate of pounded yam because loss of appetite without engaging in fasting is an ominous sign of sickness!!. God please never allow sickness beyond our strength befall us, though body is susceptible to sickness!!. I greet we Muslim for the oncoming Ramadan!!. We shall observe it with sound health and blessings in addition to its acceptance before Almighty God!!. Amen OLord!!. Good morning my people!!. Ìtumọ̀: Húùm..ìbéèrè wípé bóyá sé ẹnu san tàbí kò san, kò tọ́ sẹ́ni tó wò sùnsùn parí igbá iyán kan tán nítorí ibi kẹ́nu ó má ran oúnjẹ láì sí nínú ààwẹ̀ gan nìbẹ̀rẹ̀ àìsàn!!. Èdùmàrè jọ̀wọ́ máse jẹ́kí àìsàn tó jagbára wa lọ ó se wá, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ara kìí se okúta!!. Mo kí àwa Mùsùlùmí kú ìpalẹ̀mọ́ osù ààwẹ̀ tó wọlé tán yìí!!. Ìlera pẹ̀lú ìbùkún la ó fi gbàá pẹ̀lú ìtẹ́wọ́ gbà rẹ̀ níwájú Olúwa Ọba!!. Ó dàsẹ ni tÈdùmàrè!!. Ojúmọ́ re ẹ̀yin tèmi!!.
Posted on: Fri, 27 Jun 2014 10:49:45 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015