MO GBA LADURA FUN IWO OKAN TI O RI AMIN NLA SE, NI WAKATI ADURA YI - TopicsExpress



          

MO GBA LADURA FUN IWO OKAN TI O RI AMIN NLA SE, NI WAKATI ADURA YI WIPE, GBOGBO OTA IDILE IYA TABI TI IDILE BABA, OTA BI ORE TABI ALABAGBE, ANI EYIKEYI TOHUN KO LE JE, ANI TI WON TORI IWO TABI IDILE RE LO GBA AGBARA OSO TABI AJE, NI ORUKO TI JESU NI MO PASE WIPE KI IRU OTA BE KI O DI ENI AKANLE BO LARIN OJO MEJE, KI OLUWA FI GBOGBO AGBARA RE BA WON JA, KI IWO ATI IDILE RE SI DI ASEGUN, NI ORUKO NLA TI JESU OLUWA ATI OLUGBALA WA............
Posted on: Thu, 15 Aug 2013 08:41:12 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015