Ni Oruko Jesu mogbadura fun iwo okan tio gbagbo ni Oruko Jesu - TopicsExpress



          

Ni Oruko Jesu mogbadura fun iwo okan tio gbagbo ni Oruko Jesu wipe,Ogo de opin de, koni je tire ati awon ebi re ninu ose yi, aye koni sipe ibanuje nitori re ki odun yi to pari, aye koni torie korin oro nla leda ni abe agbara boti lewu kori, idaduro re tio fi pe kioto se igbeyawo koni mu ekun bao, idaduro re kioto to loyun ati bimo Nile oko re koni mu emire lo, idaduro re kioto lowo lowo koni mu itiju wonu aye re, fun iwo tio gbagbo, gbogbo ogun idaduro ninu irin ajo re kio lana sonu loni Ose Ayo re niyi ti aye yio kio ku Orire, ni Oruko Jesu Oluwa Ati Olugbala Wa Amin,
Posted on: Mon, 18 Nov 2013 05:24:12 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015