Nje o dara kia maafi aye ni ARA wa ki a si maa pariwo pe ijoba o - TopicsExpress



          

Nje o dara kia maafi aye ni ARA wa ki a si maa pariwo pe ijoba o nfi ara niwa.nigba ti mala hausa fee ta eran agbo ileya ni egberun lona ogun.ti iwo Omo YORUBA tio gbo ede hausa waa bami ba hausa soro titori pe emi ko gbo ede hausa.o waa nso fun mi pe egberun meedogbon ni hausa pe eran agbo.iyen 25000 instead of 20000.egbo se ijoba ni kia bu tabi awa araa wa.obe koni sele fun Eni ti o npa eran o amin.
Posted on: Wed, 09 Oct 2013 06:00:29 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015