:)Owo agbara to wa ake rii ninu omi, ire ati ogo aye enikankan to - TopicsExpress



          

:)Owo agbara to wa ake rii ninu omi, ire ati ogo aye enikankan to ti boo sonu loruko Jesu e gba pada. :)Leyi to ku ninu odun yi aye yin, idawole yin ko ni idawoduro loruko Jesu :)Gbogbo ire ojo to ti pe ninu aye yin ninu osu yi ko bere si wa si muse :)Nibi gbogbo anu Oluwa ko ni fi yin sile :)Ohun ire pata ti aye yin nfe tabi ebun odun yin losu yi ko bere si ni too yin wolo loruko Jesu :)Isegun lori ohun gbogbo a je ti yin loruko Jesu e o ni se aseti lori idawole yin, idawole yin pata ko ma tesiwaju :)Eto Olorun lori aye yin loruko Jesu ko ni daru Ni ijoba Enikankan wa pata a o ni eni awati loruko Jesu Jesu Loluwa
Posted on: Tue, 01 Oct 2013 10:56:59 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015