#hmmmmm..........O B I N R I N......... Won ni Awa Obinrin o raye - TopicsExpress



          

#hmmmmm..........O B I N R I N......... Won ni Awa Obinrin o raye wa o........ Obinrin raye wa oooooo....#fact. Sebi awa ni Adufe,Aduke,Abefe,Apeke,Asunle. Awa ni Abiyamo,abi oja gborogboro... Awa ni Iya gbogbo aye, Awa lan toju Oko Awokose wa lomo o wo Awa tun lani Omo. Olodumare funra re tun fuwa lola ninu Iwe mimo re. Omu aya wa ni gbogbo aye mu, Ibi tawa Obinrin o wa,Ibe o le dun lailai.. Kiwa lotun ku!Olodumare O seun.. Am proud of myself........#iyanimi
Posted on: Sun, 07 Dec 2014 06:25:03 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015