AgbanGBANLA ban tili banban,AgbanGBANALA ban tili banban OLORUN - TopicsExpress



          

AgbanGBANLA ban tili banban,AgbanGBANALA ban tili banban OLORUN AGBOMOLA AGBA,OBA MI ELE NLA LARIN AWON AGBAGBA NINU ORUN FUNFUN.OSUMARE TE TERE YI ITE RE KA BI IYEPE ETI OKUN.Agba tawon agbalagba pe LAgba OLORUN AGBALAGBA.OTITIMATI OLORUN TIKO SEUN TI.OBIRITIRI OBIRITIRI ENIKAN TO WA LORUN TON DARI AIYE.IGI NLA TO TO DA IGBO SE.OBA MI ADAGBA MA TEPE,OBA KORINKESE,OBA KESEKORIN,OBA MI ALAJIDEWE ORUN,TON YO BI OMO TITUN BEENI OHUN LARUGBO OJO...MOYIN O ELERI ORUN,OLORUN AJOBO,AJOSIN EDUMARE OBA MI TIN JE ASE!YOU ARE INDEED THE GREAT PHYSICIAN....IBAAAAAA OOOOOOOOO
Posted on: Thu, 07 Nov 2013 18:09:09 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015