Alaafia olohun fun gbogbo eniti oba tele ona ola; eyin omo iya mi - TopicsExpress



          

Alaafia olohun fun gbogbo eniti oba tele ona ola; eyin omo iya mi ninu islaam ; oro ton sele yi nfe apero gidi ; ejowo eyami ni eti yin ; gegebi idahun oro ti luqman ayubi so ; se omope ni 2009 ti omisore nla kaka lati di gomina ipinle yi leyin oyinlola ; jamahat tahawun gbe wa si ilu iwo nigbanaa tosi fun won ni 1million . Enikankan kolu agogo enun kiri , mo nfe ki o beere lowo alfa khidru toje igbakeji ameer tahawun pe ile iwosan to wa ni ilu oluponna leba iwo taani contractor ti omisore gbe kiko re fun , mo nbi eyin jamaha tahawun leere pe se ijoba ti musulumi ndari lora ile towa ni ori eeru fun ijo tahaawun . Ti osi tun gbe oko bus toyota 18passengers fun won . Sebi ijoba oyinlola ni . Ti kiise musulumi . Eyiti en se yi ko dara to . Emase da ija esin sile ni ipinle osun . Kini onse eyin eniyan yi na ? Se nigbati miko ti bosi ori moto ki nko owo lowo . Tabi ki npa moolu iye lofi han pe miko se ti ogbeni . Onti o pamo oju olohun too kedere . Egbo na eyin ojelu se ti kirisiteni ba tile waa wole ni ipinle osun gegebii gomina . Se iye ntumo sipe oju ti awa musulumi niye . Gegebi opolopo yin tin wi bayi pe wiwole aregbesola je idoju ti fun awon kirisiten . Se nigbati oyinlola gba ijoba lowo baba akande lojo si. se awon kirisiten ri si idojuti fun awa musulumi bi ? Emase da wahala esin sile ni ipinle osun . Ogbeni kiise oni jagidijagan . Ti aba wo awon onti awon jamaha mi anshito nso nipa pe islaam lodi si ebo ti won se opolopo apero lori re. Se esin tiwa feran elebo ni , se islaam nfe ki amaa gbe elebo ni gbowo ni ? Se siso ti aso oro ebo yi kodun moyin ninu ni ? Sebi ogben fun rare tori oro yi wa si ilu iwo . Ti asiso awon koko oro mesan fun won . Omouabi ni gomina wa won gbo oro naa ye pupo nigba naa sebi otunni awon oro to njade lenu yin . Ti eyin olugbo mi yio maa gbo ninu ibanisoro ton bo ; mofi olohun bura eo gbo winrin winrin oro . Eso ebi mi lori onti onsele yi ko tile yemi .
Posted on: Mon, 18 Aug 2014 22:17:37 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015