Awon ti o gbekele OLUWA ni idi, bikosepe o dure lailai. Bi oke nla - TopicsExpress



          

Awon ti o gbekele OLUWA ni idi, bikosepe o dure lailai. Bi oke nla ti yo Jerusalemu ka, beeli OLUWA yi awon eniyan re ka lati isinsinyi lo ati titi lailai. Nitori ti opa awon eniyan buburu ki yio ba le ipin awon olododo, ki awon olododo ki o ma ba fi owo le ese. OLUWA se rere fun awon eni-rere, ati fun awon ti aya won duro sinsin. Bi o se ti iru awon ti nwon ya is ipa ona wiwo won, OLUWA yio je ki won lo pelu awon onise ese, sugbon alaafia yio wa lori ADEOLA (Israeli)
Posted on: Sat, 19 Oct 2013 00:37:40 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015