Huum...no jungle would be so impassable that Elephant would not - TopicsExpress



          

Huum...no jungle would be so impassable that Elephant would not have access!!. Whereas no ocean would be so deep that fish would get lost within the massive water!!. God Almighty the Guidance of heaven and earth, never let us stray without trace in our struggles of life. Please grant those victims of bomb blast peace in sudden death, grant their families and acquaintances fortitude, help us stop these calamities in our nation because its those whose relations are involved that feel the pains!!. Amen O Lord!!. Were conquerors today and always!!. Good morning my people!!. Ìtumọ̀: Húùm..igbó kan kò ní dí gágá kí Àjànàkú ó má se rọ́nà kọjá!!. Bẹ́ẹ̀ ibú kan kò ní jìn dòdò kẹ̀ja ó sọnù láàrin agbamin!!. Èdùmàrè Ọba Olùsọ́ ọ̀run òun ayé, má se jẹ́kí àwa ó rin à rìn sọnù nínú ìgbòkè gbodò ayé wa. Dákun se ikú nísinmi fáwọn tó ti kú ikú òjijì nípasẹ̀ àdó olóró, tu àwọn mọ̀lẹ́bí àti ojúlùmọ̀ wọn lójú, kí O bá wa dáwọ́ àjálù ibi dúró lórílẹ̀ èdè wa nítorí àwọn ẹni tó kàn ló mọ̀!!. Ó dàsẹ ni tÈdùmàrè!!. Àwa ti dasẹ́gun lòní o. Ojúmọ́ re ẹ̀yin tèmi!!.
Posted on: Tue, 15 Apr 2014 07:29:26 +0000

Trending Topics



href="http://www.topicsexpress.com/Workforce1-has-partnered-with-a-competitive-international-company-topic-755620627813107">Workforce1 has partnered with a competitive international company
Rafael Rosales People who want to get tag LIKE Hosmar
#Certifications are the professional way to prove your skills,
Good Monday Morning... its wet outside... possible rain today...
Cheap Gizmo Dorks Executive Kit with eBook Light (Black) for the
Black Friday 2013 Yamaha Natural Sound Custom Easy-to-install

Recently Viewed Topics




© 2015