Doing Exploit for God And such as do wickedly against the - TopicsExpress



          

Doing Exploit for God And such as do wickedly against the covenants shall he compt by flatteries: but the people that do know their God shall be strong and do exploits - Dan. 11:32 The danger of the end time manifestation is that many spirit will be parading around the world seeking human vessels with which to demonstrate their power. majority of these spirits convey the mandate of the evil one. It’s unfortunate today that many people are being used by the evil spirits, being flattered by the devil and they are waxing stronger and stronger in wickedness and Rebellion. No wonder, most men/people are very smart at doing evil - many are so gifted & talented in evil strategies. They call them “Evil Genius” - like Ahithophel II Sam 16:23 Jesus says “ The children of the prince of this world are so wise in their own generation”.......... The Lord further said in Matt. 24:24- that deception will dominate the world to the extent that if the times were not shortened they will deceive the very elect. This is so because the wisdom of this world is seductive, full of flattery and rapped with enticing result that is so irresistible for many people who have been consumed in lust. I Tim. 4:1-2 . But at a time like this, when many people, young and old continue to wax stronger in wickedness and enjoying their ungodly acts and rebellious spirit- The people who know their God shall be strong and do exploits. Paul and Silas in the midst of persecution and deception were able to bring the power of God down to manifestation in Rome ( Acts 16). Though, of a truth, the king f Assyria had conquered other surrounding nations, yet Hezekiah believed that the Lord God of Israel, the one he served is different from the dead gods of other nations and will surely deliver His people from the hands of their enemies. IIKings19:8-19. Brethren, what do you know about the ‘God’ you serve? Do you think He is capable of solving your life’s mysteries and problems? Have you not been deceived by many smart and subtle evil counsellours who said you should seek help from the wise men of this world? Have you gone into covenant with the devil all because they told you his ways are fast and immediate, while God is slow to answer prayers. Note this, everyone who cares to read, that Jesus the same yesterday, today and forever- if you believe, you will surely see the glory of God- if you seek to know Him more, He will surely surround your life with miracles and exploits. The Lord do not slack with His promises- cause faithful is He who promised, He will surely fulfil His words. Just trust Him and wait patiently on Him- you will surely celebrate. “The One we serve is still the same God as of old; we are the one who has failed to serve Him like the men of old.” SISE ISE NLA FUN OLORUN Ati iru awon ti n se buburu si majemu ni, ni yio fi oro iponni mu sote; sogbon awon enia ti o mo olorun yio mu okan le, won o si ma se ise agbara- Dan. 11: 32 Ewu nla ti o wa ninu awon ifarahan igba ikehin ni pe opolopo emi ni yoo ma rin kaakiri aye; ti won o si maa wa ara eniyan ti won o lo fun ise agbara won. Pupo ninu awon emi wonyi ni won n jise fun Satani. O si se ni l’aanu loni pe opo eniyan lo je ohun elo fun eni buburu ni; Satani n fi oro iponni mu won sina won si n po si ni ise buburu ati isote. Alabajo, ti opo fi ja fafa ninu is ibi; won kun fun ebun ati talenti igbimo buburu. Won a maa pe won ni “Alagbari”- awon eeyan bi Ahitofeli. II Sam. 16:23. Jesu wipe “Awon omo alade aye yi je ologbon ni iran ti won”.....Oluwa tun tesiwaju ni Matt. 24:24 pe ni igba ikehin, etan yoo di pupo to be ge, to je pe bikose pe a ge ojo wooni kuru, a o tan awon ayanfe paapa je. Nitoripe ogbon aye kun fun opolopo adun, oro aponle ti afi etan pon lewe ti o si nira fun awon eniti okan won kun fun ifekufe lati ko ITim 4:1-2. Sugbon ni iru akoko bi eleyi, nigbati opolopo agbalagba ati omode n po si ni ise ibi ti won si n je adun aiwa-bi-Olorun ati iwa isote; awon ti o ba mo Olorun won yoo l’agbara, won o si se ise agbara. Paulu ati Sila ninu Inunibini ati ote, pe ifarahan agbara Olorun kale ni Romu nitori won mo eni ti won n sin.( Ise 16). Bakanna, bi o tile je wi pe, looto ni Oba Assyria ti segun gbogbo Ilu ti o wa ni agbegbe palastini; Hesikiah ni igbagbo ninu Olorun Isreali ti o n sin pe O yato si awon oku olorun ti awon orile-ede iyoku n sin; ati pe O to lati gbawon lowo ota. IIOba 19:8-19. Eyin ara, kini iwo mo nipa Olorun ti o n sin? Nje o ro pe O to lati tan gbogbo isoro aye re? Nje a ko ti tan o je pelu awon oro didun ati arekereke awon amoran buburu, ti n wipe ki o wa iranwo lo sodo awon ologbon aye? Nje a ko ti fi etan mu o ba Esu da majemu nitori pe won ni lesekese ati werewere ni idahun ti re, nigbati Olorun si maa n pe ko to dahun adura? E kiyesii. Gbogbo eyin ti e raye lati ka iwe yi pe; Jesu kan naa lana, Oun ni loni, Oun si ni titilae- bi iwo ba gbagbo iwo yoo ri ogo Olorun- bi iwo ba wa a ti mo O si, Oun yoo fi iyanu ati Ise Nla yio kaakiri. Nitori Oluwa ko fi ileri re jafara- nitori olooto ni eni naa ti o se ileri, yoo mu Oro Re se ni dandan. Iwo sa ti gbekele E, ki o si fi suuru duro de E- O o fo f’ayo dandan. Nitori Olorun ko yato si ti atijo awa ni a ko sin baba bi t’atijo
Posted on: Sun, 18 Aug 2013 07:15:17 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015