Falling on my kneels this morning i could only call you by your - TopicsExpress



          

Falling on my kneels this morning i could only call you by your name baba wa Oloruko egbaagbeje, Adayeda, Adasepa, Adagbejaeni, Ajisorareloruko, Adeda, Aseda, Ameda, Aweda, Alani, Akeni, Agbani, Àgbàrà-gbárá agbára to bori ohun gbogbo, Erimoerimo, Kabitikabiti, Janranjaran, Fenfefenfe, Ologo akin, Oke to bori oke, Opomulero aye, Efufu lele ti n sewe oko lalolalo, Adiitu ni o, Kayefi ni o, O wuwo koja gbigbe, O po koja kika, O gbon koja mímò, O Wibe-sebe, O yato si awon opatialaba, awon olorun yebuyebu-, Won loju won o le riran, Won leti won o le gboran, Won lese won o le fi rin, Sugbon Iwo loba toju re ri gbogbo aye lekansoso, Eleti gbooro ti oro kii kun, O wa nibigbogbo, nigbagbogbo, lekansoso, O kii leni ko to muni, O kii sàárè beeni ko si awari oye Re, Ajipojoikuda ooooo, Ayeraye ninu ayeraye Agbalagba to saaju awon agba, Erujeje, Oba ti awon oba tun nse kabiyesi fun, Enikan soso ti npe ara re ni igbimo, Oba to leto, to meto to tun feto seto ohun gbogbo,
Posted on: Thu, 21 Aug 2014 07:06:03 +0000

Trending Topics



ht:30px;">
E o Açude Castanhão, Jaguaribara,continua secando e com a pesca

Recently Viewed Topics




© 2015