Kokoro to nje ewe ṣe bi ara ewe lowa, kokoro ti njẹ obi ṣe - TopicsExpress



          

Kokoro to nje ewe ṣe bi ara ewe lowa, kokoro ti njẹ obi ṣe bi ara obi lowa, eniyan ti nṣe ni ti o ba ṣe ọta aṣe ẹbi ẹni, abanigbele tabi alabaṣiṣẹpọ awọn lo ma tete nmu ni o. Ogun aye kii ṣe ti ada ọkọ tabi ibọn rara, ogun ti nba ni ja ti a ko le foju ri, eniyan ti nṣe ni ti a jọ ma jẹun ti a o jọ mamu, Baba o dakun dabọ fi ọta han wa o laiye, eledumare aye yi dọwọ rẹ o, ma jẹ ki ọta yọ wa o. Mi o mọ pe oju ogun laye o, mi o ba ti ra ẹtu ati ibọn, mi o ba ra ibọn ẹlẹnu mẹfa, ti mo ba ri ile ẹni ti n gbogun ma fi ibẹ ṣe ibudo ija o. Be careful of ur closest friend. WORDS from committe of elders.
Posted on: Wed, 25 Sep 2013 10:33:04 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015