Oriisi okunrin to wa 1-OJOWU 2-OLOJUKOKORO 3-IKA 4-EYELE - TopicsExpress



          

Oriisi okunrin to wa 1-OJOWU 2-OLOJUKOKORO 3-IKA 4-EYELE OJOWU Iru awon okunrin yi ni won ki fe ri ki iyawo won soro pelu okunrin miran,won a fe pa ara won ti won ba gaagaa ri iyawo won pelu okunrin miran,won a jowu titi won a fi ba ohun tohun dun je,iru awon okunrin yi ni oma n ni fe iyawo,idi ni yi ti owu won fi man ba ikan je. Ale fe iru awon eyi pelu suru ati adura,tori ife to ni lo fin jowu. OLOJUKOKORO Awon okunrin yii lo ma je wi pe,iyawo ti won ti fe ki te won lorun,ti won ba ti ba sun titii won so wipe oti su awon pe ki awon lo wa obinrin mi,ti won ba si fe fe iyawo mi won ki raye iyawo tile mon awon ale ni won a ma toju,won ama sowipe awon lo si irin ajo lai mon wipe ile ale ni won lo.gbo eyin obinrin teyin na lojukokoro,pasan tafi na iyale ohun be laja fun iyawo IKA OKUNRIN Eyi ni awon okunrin ti won ko irira iyawo won,won ki se atona fun to ba se asise kan,irun awon okunrin yi i ni won ki mu inu iyawo won dun nigba ti won ba wa ninu iso kan tabi ikeji,won a sa ma se gbogbo ohun ti yio tun ma ba ninu je ni. EYELE Awon okunri bayi ni okunrin to ni amoju kuro lori gbogbo ohun ti iyawo ko ba ma se,iru okunri bayi asi da bi eni ti ko gbon,aje eni ti ki se ojukokoro ohun to ni tito,won ki fe mu inu iyawo won baje ni iseju kan,won a ma fi suru ati iwa pele gbe pelu iyawo won.eyi ni yi ti iru eyi fi dara. Ejowo nigba kugba ti a ba fe yan ololufe eje ka fi suru ati adura se. Is me Dj Lexy a.k.a S.U.G
Posted on: Sun, 23 Jun 2013 10:10:08 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015