What else does these set of useless people want in Abuja for National Conference? Dont they have insightful children that can talk to their sixth sense? Because of 12milion Naira in four months,they want to lose their lives in this rigorous exercise.. Ninu gbogbo eni ti Olorun O soore fun laye,alainitiju EDA ni number ONE.. Awon were ti o tori awon omo Naijiria lo sAbuja,ayafi tori apo ara won. Ese mefa lopin irin are... E taku kee ma ku mo... Awolowo,Azikiwe,Enahoro,Ba le wa,Macaulay ati bee bee lo da? Sio! Asiwere gbogbo! Mo dupe ti mi o ni baba ofo.
Posted on: Sun, 30 Mar 2014 12:00:31 +0000
Trending Topics
Recently Viewed Topics
© 2015