Gbo oni ni ojo isegun to gbeyi ninu osu ati odun yi ki a tori iru - TopicsExpress



          

Gbo oni ni ojo isegun to gbeyi ninu osu ati odun yi ki a tori iru ojo bayii o tun di odun to bo, gbadura yi ki o to jade so fun oluwa oba olusegun ajasegun gbogbo ogun to jami nikoko ati eyin ti o jami labenu eledumare gbemi leke gbogbo ki o to dipe won bami laye je, nitori bibeli so wipe asiwaju ogun ni ogun ma doju ko,ti a ba gbe owo joshua soke gbogbo ogun mase ni, ni oruko jesu gbogbo ogun aye re yio se danu loni, fun iwo alaye okan ti o ri amin ti o dara yi se ogun aye koni bori re okan re yio bale loruko jesu kristi. Amin, Amin ati Amin. ALAFiA!
Posted on: Tue, 30 Dec 2014 04:42:12 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015