Pelu waasi ati iroyin mecca ti a gbo ni asalat, E jo gbogbo - TopicsExpress



          

Pelu waasi ati iroyin mecca ti a gbo ni asalat, E jo gbogbo musulumi ile ola ile ayo ile gbigba adua ni ilu naa je gbogbo eyin ti e lo nba ibeje pelu iwa ti Olorun o fe ki e ye arayin wo e jo e maje ki awon elesin miran ma sope iranu ni won nse ni ile Olorun, ki Olorun san esan gbogbo ise koro ati gbangba ti a lo se ni mecca fun wa laipe laijina Allahumo Ameen.gbogbo eyin ti e de wu iwa ibaje loun ki e tuuba ki e le ri iyonu Olorun.
Posted on: Sun, 09 Nov 2014 09:47:39 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015