Now e mi aje paki but mo ti d’eyan pataki E ri bi life mi se - TopicsExpress



          

Now e mi aje paki but mo ti d’eyan pataki E ri bi life mi se change Mo d’eyan to fi 1,000 naira ra sweet ti o duro gba change E mi l’omo to ti ro pe ko le s’orire Mo woju olorun ki ni mo ri, mo r’ire E mi leni t’awon araye to ti console E mi naa re leni,ti mo n fi owo control Eyin eeyan se ri pe olorun tobi Olorun to wo shushu,olohun to se ti Mikel Obi Same olohun yii naa lo se ti okoya Olorun joo ore ni wa , joo ma je kawo faya Ti ba fe wonu yara yin tele,e ma ni pe duro na Mo n je amala ni sin, mo tigbe tuwo le na Omo Olorun ni mi,mo n’trip fun esu T’esu ba ni package men,o ma ri anu jesu
Posted on: Tue, 09 Jul 2013 14:43:43 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015